ASEGUN ATI AJOGUN NI A JE

Verse 1

A segun ati ajogun ni a je,
Nipa eje Kristi a ni isegun
B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu
Ko s’ohun to le bori agbara re

Refrain

Asegun ni wa, nipa eje Jesu
Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu
Eni t’a pa f’elese
Sibe, O wa, O njoba
Awa ju asegun lo
Awa ju asegun lo

Verse 2

A nlo l’oruko Olorun Isreal
Lati segun ese at’aisododo
Kise fun wa, sugbon Tire ni iyin
Fun ‘gbala at’isegun ta f’eje ra

Verse 3

Eni t’O ba si segun li ao fi fun
Lati je manna to t’orun wa nihin
L’orun yo sig be imo ‘pe asegun
Yo wo ‘so funfun, yo si dade wura. Amin

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s