#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics- GBOGBO AYE, GBE JESU GA

Verse 1

Gbogbo aye, gbe Jesu ga,
Angeli’, e wole fun:
E mu ade Oba Re wa,
Se l’Oba awon oba.

Verse 2

E se l’Oba, eyin Martir’
Ti n kepe n’ ite Re;
Gbe gbongbo-igi Jesse ga,
Se l’ Oba awon oba.

Verse 3

Enyin iru-omo Israel’,
Ti a ti rapada;
E ki Enit’ o gba nyin la.
Se l’ Oba awon oba.

Verse 4

Gbogbo enia elese,
Ranti ‘banuje nyin;
E te ‘kogun nyin s’ ese Re,
Se l’ Oba awon oba.

Verse 5

Ki gbogbo orile-ede,
Ni gbogbo agbaiye;
Ki nwon ki “Kabiyesi,”
Se l’ Oba awon oba.

Verse 6

A ba le pel’ awon t’ orun,
Lati ma juba Re;
K’ a ba le jo jumo korin,
Se l’ Oba awon oba.

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s