#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – NIPA IFE OLUGBALA

Verse 1:

Nipa ife Olugbala,
Ki y’ o si nkan;
Ojurere Re ki pada,
Ki y’ o si nkan.
Owon l’ eje t’ o wo wa san;
Pipe l’ edidi or’ofe;
Agbara l’owo t’o gba ni;
Ko le si nkan.

Verse 2:

Bi a wa ninu iponju,
Ki y’o si nkan:
Igbala kikun ni tiwa,
Ki y’o si nkan;
Igbekele Olorun dun;
Gbigbe inu Kristi l’ ere;
Emi si nso wa di mimo;
Ko le si nkan.

Verse 3:

Ojo ola yio dara,
Ki y’o si nkan.
Gbagbo le korin n’ iponju
Ki y’o si nkan.
A gbekele ‘fe Baba wa;
Jesu nfun wa l’ ohun gbogbo;
Ni yiye tabi ni kiku,
Ko le si nkan. 

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s