#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – WA BA MI GBE, ALE FERE LE TAN

Verse 1:

Wa ba mi gbe, ale fere le tan
Okunkun nsu, Oluwa ba mi gbe;
Bi oluranlowo miran ba ye
Iranwo alaini, wa ba mi gbe

Verse 2:

Ojo aye mi nsare lo s’opin
Ayo aye nku, ogo re nwomi
Ayida at’ibaje ni mo n ri
‘wo ti ki yipada, wa ba mi gbe

Verse 3:

Ma wa l’eru b’Oba awon oba
B’oninure, wa pelu ‘wosan Re?
Ki Ossi ma kanu fun egbe mi
Wa, ore elese, wa ba mi gbe.

Verse 4:

Mo nfe O ri, ni wakati gbogbo
Kilo le swgun esu b’ore Re?
Tal’o le se amona mi bi Re?
N’nu ‘banuje at’ayo ba mi gbe

Verse 5:

Pelu ‘bukun Re, eru ko ba mi
Ibi ko wuwo, ekun ko koro,
oro iku da? ‚segun isa da?
Un o segun sibe, b’iwo ba mi gbe.

Verse 6:

Wa ba mi gbe, ni wakati iku,
Se ‘mole mi, si toka si orun
B’aye ti nkoja, k’ile orun mo
Ni yiye, ni kiku, wa ba mi gbe.

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s