#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – JESU OLUWA OBA MI

Verse 1:

Jesu Oluwa Oba mi
Gbohun mi nigbati mo npe
Gbohun mi lati ′bugbe Re
Ro ‘jo ore – ofe sile.
Oluwa mi mo feran Re
Je ki nle ma feran Re si

Verse 2:

Jesu mo ti jafara ju
Nko se le fe O bo ti ye
EmI o se le gb’ogo Re ga
Ati ewa oruko Re.
Oluwa mi mo feran Re
Je ki nle ma feran Re si

Verse 3:

Jesu ki lo ri ninu mi
Ti ′fe naa fi po to bayi
Ore Re si mi ti po to
O ta gbogbo ero mi yo.
Oluwa mi mo feran Re
Je ki nle ma feran Re si

Verse 4:

Jesu ‘wo o je orin mi
Tire laya at’okan mi
Tire ni gbogbo emi mi
Olugbala ′wo ni temi.
Oluwa mi mo feran Re
Je ki nle ma feran Re si

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s