
#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – NINU IRIN AJO MI
Verse 1: Ninu irin ajo mi, beni mo nkorin Mo n toka si kalfari, N’ibi eje na Idanwo lode ninu, l’ota gbe dide Jesu lo nto mi lo, isegun daju Refrain: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Verse 2: … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – NINU IRIN AJO MI