#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – WA BA MI GBE, ALE FERE LE TAN

Verse 1: Wa ba mi gbe, ale fere le tanOkunkun nsu, Oluwa ba mi gbe;Bi oluranlowo miran ba yeIranwo alaini, wa ba mi gbe Verse 2: Ojo aye mi nsare lo s’opinAyo aye nku, ogo re nwomiAyida at’ibaje ni mo n ri‘wo ti ki yipada, wa ba mi gbe Verse 3: Ma wa l’eru b’Oba awon obaB’oninure, wa pelu ‘wosan Re?Ki Ossi ma kanu fun … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – WA BA MI GBE, ALE FERE LE TAN

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

Verse 1: Oluwa orun oun ayeWo niyin at’ ope ye funBawo la ba ti fe O toOnibu ore Verse 2: Orun ti nran at’ afefeGbogbo eweko nso fe ReWo l’O nmu irugbin daraOnibu ore Verse 3: Fun ara lile wa gbogboFun gbogbo ibukun ayeAwa yin O, a si dupeOnibu ore Verse 4: O ko du wa li Omo reO fi fun aye ese waOsi f’ebun … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE

Verse 1: Ose, ose rere,Iwo ojo ‘simi;O ye k’ a fi ojo kan,Fun Olorun rere;B’ ojo mi tile m’ ekun wa,Iwo n’ oju wa nu;Iwo ti s’ ojo ayo,Emi fe dide re. Verse 2: Ose, ose rere,A k’yo sise loni;A o f’ ise wa gbogboFun aisimi ola,Didan l’ oju re ma dan,‘Wo arewa ojo;Ojo mi nso ti lala,Iwo nso t’ isimi. Verse 3: Ose, ose … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE