#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

Verse 1: Oluwa orun oun ayeWo niyin at’ ope ye funBawo la ba ti fe O toOnibu ore Verse 2: Orun ti nran at’ afefeGbogbo eweko nso fe ReWo l’O nmu irugbin daraOnibu ore Verse 3: Fun ara lile wa gbogboFun gbogbo ibukun ayeAwa yin O, a si dupeOnibu ore Verse 4: O ko du wa li Omo reO fi fun aye ese waOsi f’ebun … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA

Verse 1: K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa,Ife Baba ailopin,Oju rere Emi MimoK’ o t’ oke ba lori wa. 2. Bayi l’ a le wa ni ‘repoNinu wa at’ Oluwa;T’ a si le ni ‘dapo didun,Ayo t’ aiye ko le ni. Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA

Audio+ Video: Olorun Ti Mo Gbagbo – Senwele Jesu

The prolific gospel music minister Evang. Olubukola Akinade popularly known as Senwele Jesu is out with another inspiring and prayer single titled “Olorun Ti Mo Gbagbo“. ‘Olorun Ti Mo Gbagbo’ is a prayer song to God for protection and it is of revival. The book of Psalm chapter 35 verse 24 and 25 says “Vindicate me by Your righteousness, O LORD my God, and do not let them gloat over … Continue reading Audio+ Video: Olorun Ti Mo Gbagbo – Senwele Jesu

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE

Verse 1: Ose, ose rere,Iwo ojo ‘simi;O ye k’ a fi ojo kan,Fun Olorun rere;B’ ojo mi tile m’ ekun wa,Iwo n’ oju wa nu;Iwo ti s’ ojo ayo,Emi fe dide re. Verse 2: Ose, ose rere,A k’yo sise loni;A o f’ ise wa gbogboFun aisimi ola,Didan l’ oju re ma dan,‘Wo arewa ojo;Ojo mi nso ti lala,Iwo nso t’ isimi. Verse 3: Ose, ose … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE

E BA MI JO – Oluwatunmise (Omo Baba Imole) Ft. Biyi Samuel

Oluwatunmise (ọmọ bàbà ímọ́lẹ) releases a thanksgiving song for the season’s celebration tittled “E ba Mi Jo”. The song, which features Biyi Samuel is Oluwatunmise’s anthem of gratitude for the second half of the year.  Oluwatunmise also referred to as ‘ọmọ Bàbá Ìmọ́lẹ̀’ is a music minstrel, songwriter, radio presenter, and fashion designer. A daughter of an Anglican priest, trained in a Christian home with … Continue reading E BA MI JO – Oluwatunmise (Omo Baba Imole) Ft. Biyi Samuel