#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

Verse 1: Oluwa orun oun ayeWo niyin at’ ope ye funBawo la ba ti fe O toOnibu ore Verse 2: Orun ti nran at’ afefeGbogbo eweko nso fe ReWo l’O nmu irugbin daraOnibu ore Verse 3: Fun ara lile wa gbogboFun gbogbo ibukun ayeAwa yin O, a si dupeOnibu ore Verse 4: O ko du wa li Omo reO fi fun aye ese waOsi f’ebun … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA

Verse 1: K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa,Ife Baba ailopin,Oju rere Emi MimoK’ o t’ oke ba lori wa. 2. Bayi l’ a le wa ni ‘repoNinu wa at’ Oluwa;T’ a si le ni ‘dapo didun,Ayo t’ aiye ko le ni. Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA