#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

Verse 1: Oluwa orun oun ayeWo niyin at’ ope ye funBawo la ba ti fe O toOnibu ore Verse 2: Orun ti nran at’ afefeGbogbo eweko nso fe ReWo l’O nmu irugbin daraOnibu ore Verse 3: Fun ara lile wa gbogboFun gbogbo ibukun ayeAwa yin O, a si dupeOnibu ore Verse 4: O ko du wa li Omo reO fi fun aye ese waOsi f’ebun … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OLUWA ORUN ON AIYE

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA

Verse 1: K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa,Ife Baba ailopin,Oju rere Emi MimoK’ o t’ oke ba lori wa. 2. Bayi l’ a le wa ni ‘repoNinu wa at’ Oluwa;T’ a si le ni ‘dapo didun,Ayo t’ aiye ko le ni. Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – K’ORE OFE KRIST’ OLUWA

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE

Verse 1: Ose, ose rere,Iwo ojo ‘simi;O ye k’ a fi ojo kan,Fun Olorun rere;B’ ojo mi tile m’ ekun wa,Iwo n’ oju wa nu;Iwo ti s’ ojo ayo,Emi fe dide re. Verse 2: Ose, ose rere,A k’yo sise loni;A o f’ ise wa gbogboFun aisimi ola,Didan l’ oju re ma dan,‘Wo arewa ojo;Ojo mi nso ti lala,Iwo nso t’ isimi. Verse 3: Ose, ose … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics – OSE, OSE RERE

#OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics- ONISEGUN NLA WA NIHIN

Verse 1 Onisegun nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni lara da A! Gbo ohun ti Jesu! Refrain: Iro didun lorin Seraf’, Oruko idun ni ahon. Orin to dun julo ni: Jesu! Jesu! Jesu! Verse 2 A fi gbogbo ese re ji o, A! Gbo ohun ti Jesu! Rin lo sorun lalafia, Si ba Jesu de ade. Verse 3 Gbogb’ogo fun Krist’ t’O … Continue reading #OrinIhinrere: Yoruba Hymn Lyrics- ONISEGUN NLA WA NIHIN